base-yoruba

/base-yoruba255

Celebrating Yoruba identity and creativity, proudly sponsored by /itan-world, the largest curation of West African art on-chain.

E we so,
Ewen Omo ijebu ren wa ni be,
Bon ti ri?
Ade ku bo to nlo.
Aje a ku BU gba je fun eni noni.
Ijo ayo lemi n Jo,kilo wa lese re????
A'ku ojumọ oní gbogbo akẹgbẹ mí l'ọkunrin l'obinrin asiku òpin ọsẹ, modupe pé mò jè iran (ANAGO) tan pe yoruba lóde òní iwọsọ ìran mi yayi pupo asa mi esin mi
Aku ola jimom yi edumare yio funwa ni opolopo re se ase
S'alafia ni aku dede asiko yi omo Yoruba atata asiku ayipada oungbogbo igba yi yio tuwalara ase edumare 🙏🙏🙏🙏
🌻🌻🌻🌻🌻🌻🌻🌻🌻🌻🌻
Ati je mi dowore eledua bami fere si ise mi🙏🙏🙏
Aku isimi ana,asiku aroda ojo yio tuwalara lase edumare ase🙏🙏🙏🙏ise ogbodo parun gbogbo omo Yoruba base odowo wa
Asiku asiko yi omo Yoruba atata,asiku ayipada oungbogbo igba yi yio tuwalara ase ope pupo lowo alase ikanni totawonyo Yoruba base @juujuumama fun again ti won fun wa,ese pupo momon riri yin 🙏🙏🙏🙏🙏
Sùúrùlérè

Sùúrù ni baba àyè
Aṣéjù kò f’ẹni dé ibi rere
Ìdùnnú ti ń jìnnà, bóyá ń bọ̀la,
Ṣùgbọ́n ẹnikẹ́ni tó ní sùúrù, a máa rí ire lọ́jọ́.

A dí àkókò bi ògiri kan
Bó ṣe ń tó, owó máa ń rọ̀
Ṣùgbọ́n a ní kò kọsẹ̀kìtì
Ẹni tó fọ́jú sùúrù, a ṣòwò orí ọ̀nà.

Nínú ìfaradà ni ìbùkún ń bọ̀
Aṣẹ́da máa ń gbádùn ẹni tó ní ìfaradà
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìyí, nínú òfin ìfaradà wa
Tí ẹ̀dá bá ní sùúrù, àyé máa rúmọ.

Sùúrùlérè, ìtẹ́wọ́gbà ọ̀nà rere
Èbùn tó péye ní ọwọ́ ẹni tó fẹ́ gbà
Ẹjẹ́ ká sùúrù, ká gbé àyè dáadáa
Nígbà gbogbo, sùúrù máa ní èso tó jéé.
Ojumọ re fun gbogbo wa loni. Ọsẹ ayọ ooo
Ẹku ojumọ ẹyin ara mi. Ọsẹ ayọ fun gbogbo wa.
Ẹkaarọ gbogbo ile. Aaku ọsẹ tuntun.
Mo ti n ṣiṣẹ pupọ. Mo ti n padà yin lẹ́yìn. Mo nireti pé gbogbo yin wa ni ilera.